Hirah Jahman, Jaribam, Hirah Jahman Ẹmi Mimọ, Adaba Ọrun, ẹ sọkalẹwa. Amin
Jerih moh Yah mah, Jerih moh Yah mah, Awọn Angẹli kun f’ayọ lọrun, Awọn Angẹli, Awọn Angẹli, Wọn nf’orin ayọ yin Baba l’ọrun. Amin
Nigbati fere Oluwa yio dun. Ti ise ki o si mo, A o pe ohun alaye igun merin wa, Lati fi ise won han, Niwaju Olugbala wa, Nigbati fere yio dun, emi o wa nibe Amin
Who we are
Rooted in the teachings of Jesus Christ, we provide a spiritual foundation through worship, fellowship, and service to the community.
Celestial Church of Christ, Central Cathedral Abuja (Northern and FCT Coordinator)
COPYRIGHT at Central Cathedral Media